WAEC 2018 YORUBA,HAUSA,IGBO ESSAY AND OBJECTIVE ANSWERS – MAY/JUNE – wakagist.com

ATTENTION :- PLEASE DONT COME HERE FOR FREE ANSWER… BE WARNED

YORUBA ANSWERS.

Yoruba-Obj
1CBADADACCB
11CAAACADCDA
21BCBCCCACBC
31CBACDCCACB
41BDACAAAABA
51DDCCDDBDCD
==============

IGBO OBJ :
1-10: ACADBCDBAA
11-20: CBBCDACCDD
21-30: BADCDAACAD
31-40: ADCAAABDBC
41-50: DCDDDCCCDD
51-60: DCDADBACAB

==============

Hausa

1-10CBDADCABCB
11-20BCDAADCBAC
21-30CDBBDBDABB
31-40CBCCDCCDCB
41-50BDADCAAABA
51-60CBCDBACBCD

1b Ipinya

N’llesa, Timothy Fee Koyawo E, O Lo Mu Nnkan Omokunrin Oun

Ogbeni Timothy Adekoya to gbe iyawo re, Kikelomo, lo si kootu ibile ni Ilesa ti ro ileejo pe ko tu igbeyawo olodun mewaa to wa laarin awon ka bayii lori esun pe o gbe tesoo ogun ibile kan le oun, eyi to fi mu nnkan omokunrin oun lo ti oun ko le ba obinrin mi-in sun yato si oun nikan. Esun keji ni pe iyawo oun je onigbonara, ki i fee ri obinrin mi-in pelu oun.

Ninu awijare Adekoya niwaju Adajo lo ti so pe egbelegbe owo loun ti na lati mu nnkan omokunrin oun pada bo sipo. O ro ile-ejo lati tu igbeyawo naa ka, o ni ko si ohun to le mu oun gun ori obinrin naa mo gege bii oko si aya.

Ni ti Kikelomo, o ni Adekoya je alagbere okunrin. Omo meji lo ni oun bi fun un (Timileyin, omo odun merin ati Modupe, omo odun meta), sugbon ko bikita lori ohun ti won yoo je tabi wo, afi ko maa ko awon obinrin miiran ti won so o di ileese ti won yoo ti maa pa owo wole kiri.

Iyaale ile yii ni oun ko ni nnkan kan an se pelu nnkan omo okunrin re, ko ba dara ko loo se ayewo lodo awon to n ko kiri.

ALSO READ  Okadaman Arraigned In Court For Stealing Eggrolls in Lagos State

Obinrin naa waa ro ile-ejo lati tu igbeyawo naa ka, nitori oun gan-an ti fee se bee, tawon omo meji toun bi fun un loun n ro.

Nigba ti Adajo n sun idajo re si Ojobo, osu yii, o ro olupejo ati olujejo lati je ki awon obi

won da si oro naa ko too di igba ti ile-ejo yoo gbe idajo re kale lori ipinya ti awon mejeeji fe

=================================

2a Yoruba ki silebu bayi; Silebu ni ege oro ti eemi le gbejade laisi idiwo fun eemi tin ti inu edo foro nbo

2b
i. Eja, Eka, Eje, Emu,
ii. Oja, Olo, Omu, Obo

2d
e = Eja nla nbe ni isale odo

o = Oja oba sunmo ile ifowopamo

==================================

 

 

(4a)
Kosemani ni oro ise je ninu gbolohun ede yoruba eyi tumo si pe bi ko ba si oro ise ninu gbolohun ede yoruba gbolohun naa ko le ni itumo
Bi apeere:
-Sade sun…Ki awa yo sun kuro aole mo oun ti sade se
-Baba wa nile…Bi aba yo wa ninu gbolohun yi nse lo ma dabi pe anso pe baba ile.
Awon eri meji yii fi han pe pataki oro ise ninu gbolohun ko kere

(4b)
(i)Mu je eyo oro ise pipelebe tabi alailela
(ii)Ku Ade ku je oro ise elela
(iii)da? je oro ise asebeere
(iv)ga je oroise alailela tabi ponbele
(v)Pari je oro ise alailela
(vi)Wu je oro ise ponbele tabi alailela
(vii)Jewo je oro ise alailela
(viii)Faya je oro ise alailela

 

=====================================

(12)
*Ilori- Eyi ni ọmọ ti a bi lakoko isansa iṣe iṣe oṣu;

ALSO READ  We Will Make Yorubaland A No Go Area For Militants, Gani Adams, Others Speak

* Ojo ati Aina- Eyi ni ọmọ ti a bi pẹlu awọn ayidayida okun okun ti o yika rẹ. Ti iru ọmọ ba jẹ ọkunrin, o pe ni Ojo, ati ti obirin, Aina;

* Dada- Eyi ni ọmọ ti a bi pẹlu irun gigun, nipọn ati irun ti a ko gbọdọ ge ni nigbakugba. Dada ti wa ni a npe ni Dada awuru tabi ori ori rẹ ti a si mọ pe o lagbara ati ki o ṣori;

* Oke- Eyi ni ọmọ ti a bi pẹlu awọn membran ti a ko danu ni gbogbo ara rẹ;

* Olugbodi- Eyi ni ọmọ t a bi pẹlu awọn nọmba nọmba-ikaṣe (ika mẹfa);

* Ige- Eyi ni ọmọ ti a bi pẹlu breech tabi ifarasẹ ẹsẹ ni itumọ eyi: ọmọ naa wa lati inu oyun pẹlu awọn ẹsẹ akọkọ;

* Omope- Eyi ni ọmọ ti a bi nigbamii ju akoko deede ti utero-gestation;

* Ajayi- Eyi ni ọmọ ti a bi pẹlu oju si isalẹ. Ọmọde yii ni a npe ni Ogidi olu;

* Salako (okunrin) tabi Talabi (obinrin) – Eyi ni ọmọ ti a bi pẹlu awọ ara rẹ ti a bo ni awọn membran ti a fọ;

* Abiona- Eyi ni ọmọ ti a bi lori ọna ọna nigbagbogbo nigbati iya ba lọ kuro ni ile tabi ni irin-ajo;

 

===============================================================

 

HAUSA LANGUAGE ANSWERS

3a)
Gajeran wasali shine wadda ake anfani dashi wajen Gina kalma.

3b)
-Dawa underline(a)
-tuwo underline (u)
-Nono underline (o)
-Mota underline (a)
-ruwa underline (u)
-Mata underline (a)
-nama underline (a)
-Mesa underline (e)
-Mashi underline (i)
-Mutun underline(u)
===========
4a)
Aikatu- a kalmar hausa nanufin aikin da aka aikata acikin jumla shine aikatau,

4b)
-musa Ya wanke mota
-Binta ta dafa abinci
-audu ya kama kaza
-dalibai Sun tafi makaranta
-ali ya tafi kasuwa

ALSO READ  Photo- APC Chieftain Kidnapped In Kaduna

=========

 

 

 

 

 

 

 

 

CLICK ON THE IMAGE BELOW TO VIEW THE ANSWERS 👇 👇

 
CLICK ON THE IMAGE ABOVE TO VIEW THE ANSWERS 👆 👆

 


CLICK ON THE IMAGE ABOVE TO VIEW THE ANSWERS 👆 👆
CLICK ON THE IMAGE ABOVE TO VIEW THE ANSWERS 👆 👆

IGBO
5a)
Akaraedemede bu akara e ji acho asusu mma ma a na ede ya ede ka o ga Abu a na agu ya ka o nwee nghota,dikwa uto ogugu

5b)
(i) Rikom elu (‘) bu akara edemede eji egosiputa na on were mkpuru edemede e wepuru na mkpuruokwu.

(ii) Rikom ngwu(“”) bu akara eji egosiputa okwu si n’onu mmadu puta kpomkwem n’agbakwuyeghi okwu ozo ma obu wepu okwu obula na ya.

(iii) Kpomkpom (:) bu akara edemede na egosiputa na o nwere okwu ndi ozo ga esota ya n’ azu

(iv) Akaramkpu (!) bu akara edemede eji amata na okwu e kwuru bu na mkpu ka e tiri ya.

 

===================

 

IGBO (11a) Ogbanje bu mmadu igba uwa nje maobu igba uwa uno (11b) (i) Ogbanje ulo (ii) Ogbanje mmiri (iii) Ogbanje ukwu osisi (iv) Ogbanje ukwu osisi (11c) (i) Ha na- aria oke oria karia okuko udummiri (ii) Ejiji ha na- apukari iche n’ ebe nke ihe ha di, dika iyikari ihe mmemme obara obara (iii) Ha na ebu akara e nyere ha n’ahu mgbe ha nwuru wee loghachikwa uwa ozo (iv) Ha na aga n’uzo ha a na ekwu okwu

ADS

FOLLOW US ON

Stay Updated with all Nigeria University News, Polytechnic News, JAMB UTME, Post-UTME, WAEC, NECO, NABTEB, GCE and more;


Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*